All Of Me For All Of You - Yoruba CD Cover

AJÚBÀ RE

Inú wá dùn láti fi àwon àdúrà àti orin ìjúbà láti òdò Òmòwé Noel Woodroffe àti ilé isé orin wa ti Congress MusicFactory tiise “Ajúbà re”. À únfi okàn ìsòkan wà nínú ìjúbá, ìbòwó fún, àti ìmoore wa hàn sí Olórun.

Akorin, àwon tí únko orin sínú ìwé àti àwon tínse orin sí orí ifórán, èyí ni a se láti fi ewà ara olúwa jésù Kristì hàn. Akówonjo láti òpin ayé, Caribbean, United States, Europe, Afrika, Asia, Latin America àti àwon agbègbè won, làti fowó sowópò ní sísèdá ohun èlò tí a fé pín pèlú ìjo, àti àwon onígbàgbo káàkiri àgbáyé.